Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wine: Refining of, alluded to
Àwọn ẹsẹ nípa Refining of, alluded to
Ní orí òkè yìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò ti pèsè àsè oúnjẹ àdídùn kan fún gbogbo ènìyàn àpèjẹ ti ọtí wáìnì àtijọ́ ti ẹran tí ó dára jù àti ti ọtí wáìnì tí ó gbámúṣé.