Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Waiting Upon God: Shall renew their strength
Àwọn ẹsẹ nípa Shall renew their strength
ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwa yóò sọ agbára wọn di ọ̀tun. Wọn yóò fìyẹ́ fò lókè bí idì; wọn yóò sáré àárẹ̀ kò ní mú wọn, wọn yóò rìn òòyì kò ní kọ́ wọn.