Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Waiting Upon God: The fulfillment of His word
Àwọn ẹsẹ nípa The fulfillment of His word
Nítorí ìṣípayá náà jẹ́ tí ìgbà kan tí a múra sílẹ̀ dè; yóò máa yára sí ìgbẹ̀yìn kí yóò sìsọ èké. Bí o tilẹ̀ lọ́ra, dúró dè é; nítorí, dájúdájú, yóò dé, kí yóò sí pẹ́.”