Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Waiting Upon God: Should be done with the soul

2 ẹsẹ · 68 abala

Wá "Waiting Upon God"

Àwọn ẹsẹ nípa Should be done with the soul

  1. Fún adarí orin. Fun Jedutuni. Saamu Dafidi. Nínú Ọlọ́run nìkan ni ọkàn mi ti rí ìsinmi; ìgbàlà mi ti ọ̀dọ̀ rẹ̀ wá.

  2. Nínú Ọlọ́run nìkan ni ìsinmi wà, ìwọ Ọlọ́run mi. Ìrètí mi wá láti ọ̀dọ̀ rẹ.