Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Vineyards: Compensation in kind to be made for injury done to

1 ẹsẹ · 38 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Compensation in kind to be made for injury done to

  1. “Bí ọkùnrin kan bá ń bọ́ ẹran ọ̀sìn rẹ̀ lórí pápá tàbí nínú ọgbà àjàrà, tí ó sì jẹ́ kí ó lọ jẹ nínú oko ẹlòmíràn, a ó mú kí ó san ohun ti ẹran rẹ̀ jẹ padà pẹ̀lú èyí tí ó dára jù nínú oko tàbí nínú ọgbà rẹ̀ (ẹlòmíràn padà fún un).