Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Vineyards: (Cleaning grapes of,) of the elect
Àwọn ẹsẹ nípa (Cleaning grapes of,) of the elect
Bẹ́ẹ̀ ni yóò sì rí ní orí ilẹ̀ ayé àti láàrín àwọn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú, gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí a lu igi olifi, tàbí gẹ́gẹ́ bí i pàǹtí tí ó ṣẹ́kù lẹ́yìn tí a kórè èso tán.