Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Travellers: Generally commenced their journey early in the morning
Àwọn ẹsẹ nípa Generally commenced their journey early in the morning
Ní ọjọ́ kẹrin, wọ́n dìde ní òwúrọ̀ kùtùkùtù òun sì múra láti padà lọ, ṣùgbọ́n baba ọmọbìnrin náà wí fún àna rẹ̀ pé, “Fi ohun jíjẹ díẹ̀ gbé inú ró nígbà náà kí ìwọ máa lọ.”