Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Travellers: Frequently took leave of them with sorrow
Àwọn ẹsẹ nípa Frequently took leave of them with sorrow
Gbogbo wọn sì sọkún gidigidi, wọ́n sì rọ̀ mọ́ Paulu lọ́rùn, wọ́n sì fi ẹnu kò ó lẹ́nu.
Nígbà tí a sì ti dágbére fún ara wa, a bọ́ sí ọkọ̀; bẹ́ẹ̀ ni àwọn sì padà lọ sí ilé wọn.