Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Timothy: Circumcised; becomes Paul's companion

2 ẹsẹ · 18 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Circumcised; becomes Paul's companion

  1. Òun ni Paulu fẹ́ kí ó bá òun lọ; ó sì mú un, ó sì kọ ọ́ ní ilà, nítorí àwọn Júù tí ó wà ní agbègbè wọ̀nyí, nítorí gbogbo wọn mọ̀ pé, Giriki ni baba rẹ̀.

  2. Awa sì rán Timotiu, arákùnrin àti alábáṣiṣẹ́pọ̀ wa nínú Ọlọ́run nínú ìyìnrere Kristi, láti fi ẹsẹ yín múlẹ̀, àti láti tù yín nínú ní ti ìgbàgbọ́ yín.