Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Time: The time of restitution of all things
Àwọn ẹsẹ nípa The time of restitution of all things
Ẹni tí ọ̀run kò lé ṣàìmá gbà títí di ìgbà ìmúpadà ohun gbogbo, tí Ọlọ́run ti sọ láti ẹnu àwọn wòlíì rẹ̀ mímọ́ tí wọn ti ń bẹ nígbà tí ayé ti ṣẹ̀.