Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Time: All God's purposes fulfilled in due time

2 ẹsẹ · 44 abala

Àwọn ẹsẹ nípa All God's purposes fulfilled in due time

  1. Ó sì kéde wí pé, “Àkókò náà dé wàyí, ìjọba Ọlọ́run kù sí dẹ̀dẹ̀. Ẹ yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ yín, kí ẹ sì gba ìyìnrere yìí gbọ́.”

  2. Ṣùgbọ́n nígbà tí àkókò kíkún náà dé, Ọlọ́run rán ọmọ rẹ̀ jáde wá, ẹni tí a bí nínú obìnrin tí a bí lábẹ́ òfin.