Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Wisdom of God: Wisdom of saints is derived from

1 ẹsẹ · 36 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Wisdom of saints is derived from

  1. Ìwọ Esra, ní ìbámu pẹ̀lú ọgbọ́n Ọlọ́run rẹ̀, èyí tí ó ní, yan àwọn adájọ́ àgbà àti àwọn onídàájọ́ láti máa ṣe ìdájọ́ fún àwọn ènìyàn agbègbè Eufurate, gbogbo àwọn tí ó mọ òfin Ọlọ́run rẹ. Ìwọ yóò sì kọ́ ẹnikẹ́ni tí kò mọ̀ àwọn òfin náà.