Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Wisdom of God: The minutest matters
Àwọn ẹsẹ nípa The minutest matters
Ológoṣẹ́ méjì kọ́ ni à ń tà ní owó idẹ wẹ́wẹ́ kan? Síbẹ̀ kò sí ọ̀kan nínú wọn tí yóò ṣubú lu ilẹ̀ lẹ́yìn Baba yin.
Àti pé gbogbo irun orí yín ni a ti kà pé.