Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Zebulun: Encamped under the standard of Judah, east of the tabernacle
Àwọn ẹsẹ nípa Encamped under the standard of Judah, east of the tabernacle
Ní ìlà-oòrùn, ní ìdojúkọ àtiyọ oòrùn: ni kí ìpín ti Juda pa ibùdó wọn sí lábẹ́ ọ̀págun wọn. Olórí Juda ni Nahiṣoni ọmọ Amminadabu.
Ẹ̀yà Sebuluni ni yóò tẹ̀lé e. Olórí Sebuluni ni Eliabu ọmọ Heloni.