Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Zebulun: Descended from Jacob's tenth son
Àwọn ẹsẹ nípa Descended from Jacob's tenth son
Lea sì tún lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kẹfà fún Jakọbu.
Nígbà náà ni Lea tún wí pé “Ọlọ́run ti fún mi ní ẹ̀bùn iyebíye, nígbà yìí ni ọkọ mi yóò máa bu ọlá fún mi.” Nítorí náà ni ó ṣe pe orúkọ rẹ̀ ni Sebuluni.