Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Tribe Of Simeon: Descended from Jacob's second son by Leah
Àwọn ẹsẹ nípa Descended from Jacob's second son by Leah
Ó sì tún lóyún, ó bí ọmọkùnrin kan. Ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Simeoni, wí pé, “Nítorí tí Olúwa ti gbọ́ pé a kò fẹ́ràn mi, ó sì fi èyí fún mi pẹ̀lú.”