Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Righteousness of God: Ascribe, to him

2 ẹsẹ · 46 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Ascribe, to him

  1. Èmi ó mú ìmọ̀ mi ti ọ̀nà jíjìn wá, èmi ó sì fi òdodo fún Ẹlẹ́dàá mi.

  2. “Olúwa ìwọ ni olódodo, ṣùgbọ́n báyìí ìtìjú dé bá àwọn ènìyàn Juda, àwọn ènìyàn Jerusalẹmu àti gbogbo Israẹli ní gbogbo orílẹ̀-èdè tí ìwọ ti fọ́n wa ká sí nítorí àìṣòótọ́ ọ wa sí ọ.