Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Righteousness of God: His judgments

3 ẹsẹ · 46 abala

Àwọn ẹsẹ nípa His judgments

  1. Ìbẹ̀rù Olúwa mọ́, ó ń faradà títí láéláé. Ìdájọ́ Olúwa dájú òdodo ni gbogbo wọn.

  2. Èmi yóò yìn ọ́ pẹ̀lú ọkàn ìdúró ṣinṣin bí èmi bá ti kọ́ òfin òdodo rẹ̀.

  3. Ní àárín ọ̀gànjọ́ òru èmi dìde láti fi ọpẹ́ fún ọ nítorí òfin òdodo rẹ.