Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Power of Christ: Rests upon saints
Àwọn ẹsẹ nípa Rests upon saints
Òun sì wí fún mi pé, “Oore-ọ̀fẹ́ mi tó fún ọ, nítorí pé a sọ agbára mi di pípé nínú àìlera.” Nítorí náà tayọ̀tayọ̀ ni èmi ó kúkú máa fi ṣògo nínú àìlera mi, kí agbára Kristi lè máa gbé inú mi.