Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Power of Christ: Destroying the works of Satan
Àwọn ẹsẹ nípa Destroying the works of Satan
Ẹni tí ó ba ń dẹ́ṣẹ̀ tí èṣù ni; nítorí láti àtètèkọ́ṣe ni èṣù ti ń dẹ́ṣẹ̀. Nítorí èyí ni Ọmọ Ọlọ́run ṣe farahàn, kí ó lè pa iṣẹ́ èṣù run.