Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The, or Immediate Government By God Theocracy: The emblem of the divine presence appeared over the tabernacle during

2 ẹsẹ · 15 abala

Wá "The, or Immediate Government By God Theocracy"

Àwọn ẹsẹ nípa The emblem of the divine presence appeared over the tabernacle during

  1. Ní ọjọ́ tí wọ́n gbé àgọ́ ró, èyí tí í ṣe àgọ́ ẹ̀rí, dúró, ìkùùkuu àwọsánmọ̀ bò ó mọ́lẹ̀. Ìkùùkuu náà sì dàbí iná ní orí àgọ́ láti ìrọ̀lẹ́ títí di òwúrọ̀.

  2. Bẹ́ẹ̀ ni ó sì rí nígbà gbogbo; ìkùùkuu bò ó, àti pé ní alẹ́ ìrísí rẹ̀ sì dàbí iná.