Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The New Birth: The word of God

2 ẹsẹ · 35 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The word of God

  1. Ó pinnu láti fi ọ̀rọ̀ òtítọ́ bí wa kí àwa kí ó le jẹ́ àkọ́so nínú ohun gbogbo tí ó dá.

  2. Bí a ti tún yín bí, kì í ṣe láti inú ìdíbàjẹ́ wá, bí kò ṣe èyí ti kì í díbàjẹ́ nípa ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí ń bẹ láààyè tí ó sì dúró.