Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Levites: Not numbered with Israel
Àwọn ẹsẹ nípa Not numbered with Israel
A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù.
Nítorí Olúwa ti sọ fún Mose pé,
“Ìwọ kò gbọdọ̀ ka ẹ̀yà Lefi, tàbí kí o kà wọ́n mọ́ àwọn ọmọ Israẹli.
A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù.
Nítorí Olúwa ti sọ fún Mose pé,
“Ìwọ kò gbọdọ̀ ka ẹ̀yà Lefi, tàbí kí o kà wọ́n mọ́ àwọn ọmọ Israẹli.