Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Levites: Numbered separately after the people from a month old
Àwọn ẹsẹ nípa Numbered separately after the people from a month old
Nígbà náà ni Olúwa sọ fún Mose ní aginjù Sinai pé,
“Ka àwọn ọmọ Lefi nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn kí o ka gbogbo ọmọkùnrin láti ọmọ oṣù kan sókè.”
Mose sì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa ti pa á láṣẹ fún un.