Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Anakim: Driven from Kirjathsepher or Debir by Othniel

3 ẹsẹ · 13 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Driven from Kirjathsepher or Debir by Othniel

  1. Ó sì wọ́de ogun láti ibẹ̀ lọ bá àwọn ènìyàn tí ń gbé ní Debiri (tí à ń pè ní Kiriati-Seferi nígbà kan rí).

  2. Kalebu sì wí pé, “Èmi yóò fi ọmọbìnrin mi Aksa fún ọkùnrin tí ó bá kọlu Kiriati-Seferi, tí ó sì gbà á ní ìgbéyàwó.”

  3. Otnieli ọmọ Kenasi, arákùnrin Kalebu, sì gbà á, báyìí ni Kalebu sì fi ọmọbìnrin rẹ̀ Aksa fún un ní ìyàwó.