Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Altar of Burnt Offering: The Jews condemned for swearing lightly by

2 ẹsẹ · 30 abala

Wá "The Altar of Burnt Offering"

Àwọn ẹsẹ nípa The Jews condemned for swearing lightly by

  1. Àti pé, ẹnikẹ́ni tó bá fi pẹpẹ búra, kò jámọ́ nǹkan, ṣùgbọ́n bí ẹnikẹ́ni tí ó ba fi ẹ̀bùn tí ó wà lórí rẹ̀ búra, ó di ajigbèsè.

  2. Ẹ̀yin aláìmòye afọ́jú wọ̀nyí! Èwo ni ó pọ̀jù: ẹ̀bùn tí ó wà lórí pẹpẹ ni tàbí pẹpẹ fúnra rẹ̀ tí ó sọ ẹ̀bùn náà di mímọ́?