Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Strangers in Israel: Might purchase Hebrew servants subject to release

2 ẹsẹ · 33 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Might purchase Hebrew servants subject to release

  1. “ ‘Bí àlejò kan láàrín yín tàbí ẹni tí ń gbé àárín yín fún ìgbà díẹ̀ bá lọ́rọ̀ tí ọmọ Israẹli sì tálákà dé bi pé ó ta ara rẹ̀ lẹ́rú fún àlejò tàbí ìdílé àlejò náà.

  2. Ó lẹ́tọ̀ọ́ si ki a rà á padà lẹ́yìn ìgbà tí ó ti ta ara rẹ̀. Ọ̀kan nínú ìbátan rẹ̀ le è rà á padà.