Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Spirituality: Brings thirst for heavenly blessings

2 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Brings thirst for heavenly blessings

  1. Alábùkún fún ni àwọn tí ebi ń pa tí òǹgbẹ ń gbẹ́ nítorí òdodo, nítorí wọn yóò yó.

  2. Ẹ má ṣe ṣiṣẹ́ fún oúnjẹ tí ń ṣègbé, ṣùgbọ́n fún oúnjẹ tí ó wà títí di ayé àìnípẹ̀kun, èyí tí Ọmọ Ènìyàn yóò fi fún yín. Nítorí pé òun ni, àní Ọlọ́run Baba ti fi èdìdì dì í.”