Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Snow: In Uz 3 ẹsẹ · 4 abala Wá "Snow" Gbogbo 8 Figurative of purity 3 In Uz 3 In Palestine 1 On Mount Lebanon 1 Àwọn ẹsẹ nípa In Uz Jobu 6:16Tí ó dúdú nítorí omi dídì, àti níbi tí yìnyín dídì gbé di yíyọ́.Jobu 9:30Bí mo tilẹ̀ fi ọṣẹ dídì wẹ ara mi, tí mo fi omi aró wẹ ọwọ́ mi mọ́,Jobu 37:6Nítorí tí ó wí fún yìnyín pé, ‘Ìwọ rọ̀ sílẹ̀ ayé,’ àti pẹ̀lú fún ọwọ́ òjò, ‘Fún òjò ńlá agbára rẹ̀.’