Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Slime: Used at Babel

1 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Used at Babel

  1. Wọ́n sì wí fún ara wọn pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a mọ bíríkì kí a sì sún wọ́n jìnà.” Bíríkì ni wọ́n ń lò ní ipò òkúta, àti ọ̀dà ilẹ̀ tí wọn ń lò láti mú wọn papọ̀ dípò ẹfun (òkúta láìmù tí wọ́n fi ń ṣe símẹ́ńtì àti omi).