Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shields: In times of peace were hung up in towers or armouries

2 ẹsẹ · 23 abala

Àwọn ẹsẹ nípa In times of peace were hung up in towers or armouries

  1. Ọrùn rẹ dàbí ilé ìṣọ́ Dafidi, tí a kọ́ pẹ̀lú ìhámọ́ra; lórí rẹ̀ ni a fi ẹgbẹ̀rún (1,000) àpáta kọ́, gbogbo wọn jẹ́ àṣà àwọn alágbára.

  2. “ ‘Àwọn ènìyàn Persia, Ludi àti Puti wà nínú jagunjagun rẹ àwọn ẹgbẹ́ ọmọ-ogun rẹ. Wọ́n gbé asà àti àṣíborí wọn ró sára ògiri rẹ, wọn fi ẹwà rẹ hàn.