Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shepherds: Had hired keepers under them

1 ẹsẹ · 24 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Had hired keepers under them

  1. Ní àárọ̀ kùtùkùtù Dafidi fi agbo ẹran rẹ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn olùtọ́jú, ó di ẹrù, ó sì mú ọ̀nà rẹ̀ pọ̀n gẹ́gẹ́ bí Jese ti sọ fún un. Ó dé ibùdó bí àwọn ọmọ-ogun ti ń lọ láti dúró ní ipò wọn ní ojú ogun, wọ́n hó ìhó ogun.