Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shepherd: David, the shepherd, defends his flock against a lion and a bear

2 ẹsẹ · 12 abala

Àwọn ẹsẹ nípa David, the shepherd, defends his flock against a lion and a bear

  1. Ṣùgbọ́n Dafidi sọ fún Saulu pé, “Ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ ti ń tọ́jú agbo àgùntàn baba rẹ̀. Nígbà tí kìnnìún tàbí àmọ̀tẹ́kùn bá wá láti wá gbé àgùntàn láti inú igbó.

  2. Mo sá tẹ̀lé e, mo lù ú, mo sì gba àgùntàn náà kúrò lẹ́nu rẹ̀. Nígbà tí ó kọjú sí mi, mo fi irun rẹ̀ gbá a mú, mo sì lù ú mo sì pa á.