Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Serug: An ancestor of Abraham

5 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa An ancestor of Abraham

  1. Nígbà tí Reu pé ọdún méjìlélọ́gbọ̀n ni ó bí Serugu.

  2. Reu tún wà láààyè lẹ́yìn tí ó bí Serugu fún igba ọdún ó lé méje (207), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mìíràn.

  3. Nígbà tí Serugu pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Nahori.

  4. Serugu sì wà láààyè fún igba ọdún lẹ́yìn tí ó bí Nahori, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

  5. Serugu, Nahori, Tẹra,