Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Self-Righteousness: Lawyer

2 ẹsẹ · 30 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Lawyer

  1. Sì kíyèsi i amòfin kan dìde, ó ń dán an wò, ó ní, “Olùkọ́, kín ni èmi ó ṣe kí èmi lè jogún ìyè àìnípẹ̀kun?”

  2. Ṣùgbọ́n ó ń fẹ́ láti da ara rẹ̀ láre, ó wí fún Jesu wí pé, “Ta ha sì ni ẹnìkejì mi?”