Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Samuel: Shelters David when escaping from Saul
Àwọn ẹsẹ nípa Shelters David when escaping from Saul
Nígbà tí Dafidi ti sálọ tí ó sì ti bọ́, ó sì lọ sọ́dọ̀ Samuẹli ní Rama ó sì sọ gbogbo ohun tí Saulu ti ṣe fún un. Òun àti Samuẹli lọ sí Naioti láti dúró níbẹ̀.