Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Samuel: Death of; the lament for him

1 ẹsẹ · 22 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Death of; the lament for him

  1. Samuẹli sì kú; gbogbo ènìyàn Israẹli sì kó ara wọn jọ, wọ́n sì sọkún rẹ̀ wọ́n sì sin ín nínú ilé rẹ̀ ní Rama. Dafidi sì dìde, ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí ijù Parani.