Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Red Sea: Boundary of the promised land

1 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Boundary of the promised land

  1. “Èmi yóò fi ìdí òpin ààlà ilẹ̀ rẹ lélẹ̀ láti etí Òkun Pupa títí dé òkun àwọn ara Filistini, láti aṣálẹ̀ títí dé etí odò Eufurate, Èmi yóò fa àwọn ènìyàn ti ń gbé ilẹ̀ náà lé ọ lọ́wọ́, ìwọ yóò sì lé wọn jáde kúrò ní iwájú rẹ.