Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Purification: By fire, for things that resist fire

1 ẹsẹ · 13 abala

Àwọn ẹsẹ nípa By fire, for things that resist fire

  1. Ohunkóhun tí ó lè la iná ni kí ẹ̀yin ó mú la iná, nígbà náà ni yóò jẹ́ mímọ́. Ṣùgbọ́n ẹ yóò fi omi ìyàsímímọ́ sọ ọ́ di mímọ́. Àti gbogbo ohun tí kò lè la iná kọjá ni kí a mú la inú omi.