Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Publicans: Embraced the gospel

1 ẹsẹ · 19 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Embraced the gospel

  1. “Nínú àwọn méjèèjì yìí, èwo ni ó ṣe ìfẹ́ baba wọn?” Gbogbo wọn sì fohùn ṣọ̀kan pé, “Èyí ẹ̀gbọ́n ni.” Jesu wí fún wọn pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, àwọn agbowó òde àti àwọn panṣágà yóò wọ ìjọba ọ̀run síwájú yín.