Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prudence: Sergius Paulus
Àwọn ẹsẹ nípa Sergius Paulus
Ó wà lọ́dọ̀ Segiu Paulusi baálẹ̀ ìlú náà tí í ṣe amòye ènìyàn. Òun náà ni ó ránṣẹ́ pe Barnaba àti Saulu, nítorí tí ó fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.