Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prudence: Fails in times of perplexity
Àwọn ẹsẹ nípa Fails in times of perplexity
Nípa Edomu. Èyí ní ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: “Ṣe kò ha sí ọgbọ́n mọ́ ni Temani? Ṣé a ti ké ìmọ̀ràn kúrò ní ọ̀dọ̀ olóyè? Ṣé ọgbọ́n wọn ti bàjẹ́ bí?