Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Procrastination: Felix

1 ẹsẹ · 15 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Felix

  1. Bí Paulu sì tí ń sọ àsọyé nípa tí òdodo àti àìrékọjá àti ìdájọ́ tí ń bọ̀, ẹ̀rù ba Feliksi, ó dáhùn wí pé, “Èyí tí o sọ nì tó ná! Máa lọ nísinsin yìí ná. Nígbà tí mo bá sì ní àkókò tí ó wọ̀, èmi ó ránṣẹ́ pè ọ́.”