Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Perizzites: Territory of, given to Abraham

3 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Territory of, given to Abraham

  1. àti ti ará Hiti, àti ti ará Peresi, àti ti ará Refaimu.

  2. Èmi sì ti sọ̀kalẹ̀ wá láti gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn ará Ejibiti, àti láti mú wọn gòkè kúrò ní ilẹ̀ náà lọ sí ilẹ̀ tí ó dára tí ó sì ní ààyè, àní ilẹ̀ tí ó ń sàn fún wàrà àti oyin; ibùgbé àwọn ará Kenaani, ará Hiti, Amori, Peresi, Hifi àti Jebusi.

  3. Angẹli mi yóò lọ níwájú rẹ, yóò sì mú ọ dé ọ̀dọ̀ àwọn ará: Amori, Hiti, Peresi, Kenaani, Hifi àti Jebusi, èmi a sì gé wọn kúrò.