Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Or Copper Brass: Cleansed by fire

3 ẹsẹ · 43 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Cleansed by fire

  1. Eleasari àlùfáà sì wí fún àwọn olórí ogun náà pé, “Èyí ní ìlànà òfin tí Olúwa fi lélẹ̀ ní àṣẹ fún Mose.

  2. Kìkì i wúrà, fàdákà, idẹ, irin, idẹ àti òjé.

  3. Ohunkóhun tí ó lè la iná ni kí ẹ̀yin ó mú la iná, nígbà náà ni yóò jẹ́ mímọ́. Ṣùgbọ́n ẹ yóò fi omi ìyàsímímọ́ sọ ọ́ di mímọ́. Àti gbogbo ohun tí kò lè la iná kọjá ni kí a mú la inú omi.