Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ono: A town of Benjamin.

3 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A town of Benjamin.

  1. Àwọn ọmọ Elipali: Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.)

  2. Sanballati àti Geṣemu rán iṣẹ́ yìí sí mi pé, “Wá jẹ́ kí a jọ pàdé pọ̀ nínú ọ̀kan lára àwọn ìletò ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ono.” Ṣùgbọ́n wọ́n ń gbèrò láti ṣe mí ní ibi;

  3. ní Lodi àti Ono, àti ní àfonífojì àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà.