Lod
31.9500, 34.8900 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Lod
Àwọn ọmọ Elipali: Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.)
Lodi, Hadidi àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé márùn-ún (725)
Lodi, Hadidi, àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé ọ̀kan (721)
ní Lodi àti Ono, àti ní àfonífojì àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà.