Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Oaths: To take, in truth, judgment, &c
Àwọn ẹsẹ nípa To take, in truth, judgment, &c
Tí ó bá jẹ́ lóòtítọ́ àti òdodo ni ìwọ búra. Nítòótọ́ bí Olúwa ti wà láààyè, nígbà náà ni orílẹ̀-èdè yóò di alábùkún fún nípasẹ̀ rẹ, àti nínú rẹ̀ ni wọn yóò ṣògo.”