Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nimrod
Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì
Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.
Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nimrodu, ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.”
Kuṣi sì bí Nimrodu ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.