Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Music: In commemorating great men

1 ẹsẹ · 57 abala

Àwọn ẹsẹ nípa In commemorating great men

  1. Jeremiah sì pohùnréré ẹkún fún Josiah, gbogbo àwọn akọrin ọkùnrin àti gbogbo àwọn akọrin obìnrin sì ń sọ ti Josiah nínú orin ẹkún wọn ní Israẹli títí di òní. Èyí sì di àṣà ní Jerusalẹmu, a sì kọ ọ́ sínú àwọn orin ẹkún.